Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 10:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Mata kò rójú nítorí aájò tí ó ń ṣe nípa oúnjẹ. Ni Mata bá wá, ó ní, “Alàgbà, arabinrin mi fi èmi nìkan sílẹ̀ láti máa tọ́jú oúnjẹ, o sì dákẹ́ ò ń wò ó níran! Sọ fún un kí ó wá ràn mí lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Luku 10

Wo Luku 10:40 ni o tọ