Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 10:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Mata ní arabinrin kan tí ó ń jẹ́ Maria. Maria yìí jókòó lẹ́bàá ẹsẹ̀ Jesu, ó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Luku 10

Wo Luku 10:39 ni o tọ