Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 10:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó di ọjọ́ keji, ó yọ owó fadaka meji jáde, ó fún olùtọ́jú ilé èrò, ó ní, ‘Ṣe ìtọ́jú ọkunrin yìí. Ohun tí o bá ná lé e lórí, n óo san án fún ọ nígbà tí mo bá pada dé.’

Ka pipe ipin Luku 10

Wo Luku 10:35 ni o tọ