Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 10:34 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá lọ sọ́dọ̀ rẹ̀, ó fi òróró ati ọtí waini sí ojú ọgbẹ́ rẹ̀, ó sì fi aṣọ wé e. Ó gbé ọkunrin náà ka orí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ tí ó gùn. Ó gbé e lọ sí ilé èrò níbi tí ó ti ṣe ìtọ́jú rẹ̀.

Ka pipe ipin Luku 10

Wo Luku 10:34 ni o tọ