Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Luku 10:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Amòfin kan wá, ó fi ìbéèrè yìí wá Jesu lẹ́nu wò. Ó ní, “Olùkọ́ni, kí ni kí n ṣe kí n lè jogún ìyè ainipẹkun?”

Ka pipe ipin Luku 10

Wo Luku 10:25 ni o tọ