Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 7:39 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti so obinrin pọ̀ mọ́ ọkọ rẹ̀ níwọ̀n ìgbà tí ọkọ rẹ̀ bá wà láàyè. Ṣugbọn bí ọkọ rẹ̀ bá kú, ó ní òmìnira láti tún ní ọkọ mìíràn tí ó bá fẹ́. Ṣugbọn onigbagbọ nìkan ní ó lè fẹ́.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 7

Wo Kọrinti Kinni 7:39 ni o tọ