Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 7:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbolohun kan, ẹni tí ó bá gbé wundia rẹ̀ ní iyawo kò ṣe nǹkan burúkú. Ṣugbọn ẹni tí kò bá gbé e ní iyawo ni ó ṣe ohun tí ó dára jùlọ.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 7

Wo Kọrinti Kinni 7:38 ni o tọ