Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 7:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ní ọ̀rọ̀ fún ẹ̀yin yòókù, (èrò tèmi ni o, kì í ṣe ọ̀rọ̀ Oluwa wa.) Bí ọkunrin onigbagbọ kan bá ní aya tí kì í ṣe onigbagbọ, tí ó bá wu aya rẹ̀ láti máa bá a gbé, kí ọkọ má ṣe kọ̀ ọ́.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 7

Wo Kọrinti Kinni 7:12 ni o tọ