Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 15:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn nǹkan ẹlẹ́mìí tí ń fò lófuurufú wà. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ti orí ilẹ̀ wà. Ọ̀tọ̀ ni ẹwà ti àwọn tí ń fò lófuurufú. Ọ̀tọ̀ ni ẹwà àwọn ti orí ilẹ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:40 ni o tọ