Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 15:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ẹran-ara kì í ṣe oríṣìí kan náà. Ọ̀tọ̀ ni ẹran-ara eniyan, ọ̀tọ̀ ni ti ẹranko, ọ̀tọ̀ ni ti ẹyẹ, ọ̀tọ̀ ni ti ẹja.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:39 ni o tọ