Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 15:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ará, mo fẹ́ ran yín létí ọ̀rọ̀ ìyìn rere tí mo fi waasu fun yín, tí ẹ gbà, tí ẹ sì bá dúró.

2. Nípa ìyìn rere yìí ni a fi ń gbà yín là, tí ẹ bá dì mọ́ ọ̀rọ̀ ìyìn rere tí mo fi waasu fun yín, bí bẹ́ẹ̀ kọ́ asán ni igbagbọ yín.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15