Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 15:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ohun kinni tí ó ṣe pataki jùlọ tí èmi fúnra mi kọ́, tí mo sì fi kọ́ yín ni pé Kristi kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa, gẹ́gẹ́ bí Ìwé Mímọ́ ti wí.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 15

Wo Kọrinti Kinni 15:3 ni o tọ