Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Kinni 10:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnìkan ninu àwọn alaigbagbọ bá pè yín wá jẹun, tí ẹ bá gbà láti lọ, ẹ jẹ ohunkohun tí ó bá gbé kalẹ̀ níwájú yín láì wádìí ohunkohun, kí ẹ̀rí-ọkàn yín lè mọ́.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 10

Wo Kọrinti Kinni 10:27 ni o tọ