Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 13:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Òtítọ́ ni pé a kàn án mọ́ agbelebu ní àìlera, ṣugbọn ó wà láàyè nípa agbára Ọlọrun. Òtítọ́ ni pé àwa náà jẹ́ aláìlera pẹlu rẹ̀, ṣugbọn a óo wà láàyè pẹlu rẹ̀ nípa agbára Ọlọrun ninu ìbálò wa pẹlu yín.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 13

Wo Kọrinti Keji 13:4 ni o tọ