Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 13:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí mo ti sọ fún àwọn tí wọ́n ti ṣẹ̀ tẹ́lẹ̀ ati àwọn yòókù, tí mo tún sọ nígbà tí mo wá sọ́dọ̀ yín lẹẹkeji, bẹ́ẹ̀ ni mo tún ń sọ nisinsinyii tí n kò sí lọ́dọ̀ yín, pé nígbà tí mo bá tún dé, n kò ní ṣojú àánú;

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 13

Wo Kọrinti Keji 13:2 ni o tọ