Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 13:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí tí mo fi ń kọ gbogbo nǹkan wọnyi nígbà tí n kò sí lọ́dọ̀ yín ni pé nígbà tí mo bá dé, kí n má baà fi ìkanra lo àṣẹ tí Oluwa ti fi fún mi láti fi mú ìdàgbà wá, kì í ṣe láti fi wo yín lulẹ̀.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 13

Wo Kọrinti Keji 13:10 ni o tọ