Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 12:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, kí n má baà ṣe ìgbéraga nípa àwọn ìfihàn tí ó ga pupọ wọnyi, a fi ẹ̀gún kan sí mi lára, ẹ̀gún yìí jẹ́ iranṣẹ Satani, láti máa gún mi, kí n má baà gbéraga.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 12

Wo Kọrinti Keji 12:7 ni o tọ