Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Kọrinti Keji 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

A ṣe bí wọ́n tí dá wa lẹ́bi ikú ni. Kí á má baà gbẹ́kẹ̀lé ara wa, bíkòṣe Ọlọrun, ni ọ̀rọ̀ fi rí bẹ́ẹ̀. Nítorí Ọlọrun níí jí òkú dìde.

Ka pipe ipin Kọrinti Keji 1

Wo Kọrinti Keji 1:9 ni o tọ