Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 8:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n gbọ́, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí lọ lọ́kọ̀ọ̀kan, àwọn àgbààgbà ni wọ́n kọ́ lọ. Gbogbo wọ́n bá túká pátá láìku ẹnìkan. Ó wá ku obinrin yìí nìkan níbi tí ó dúró sí.

Ka pipe ipin Johanu 8

Wo Johanu 8:9 ni o tọ