Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 8:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu gbé ojú sókè, ó bi obinrin náà pé, “Obinrin, àwọn dà? Ẹnìkan ninu wọn kò dá ọ lẹ́bi?”

Ka pipe ipin Johanu 8

Wo Johanu 8:10 ni o tọ