Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 17:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba mímọ́, ayé kò mọ̀ ọ́, ṣugbọn èmi mọ̀ ọ́, ó ti yé àwọn wọnyi pé ìwọ ni ó rán mi níṣẹ́.

Ka pipe ipin Johanu 17

Wo Johanu 17:25 ni o tọ