Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 17:24 BIBELI MIMỌ (BM)

“Baba, mo fẹ́ kí àwọn tí o fi fún mi wà pẹlu mi níbi tí èmi gan-an bá wà, kí wọ́n lè máa wo ògo tí o ti fi fún mi, nítorí o ti fẹ́ràn mi kí á tó fi ìpìlẹ̀ ayé sọlẹ̀.

Ka pipe ipin Johanu 17

Wo Johanu 17:24 ni o tọ