Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 10:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnikẹ́ni kò gba ẹ̀mí mi, ṣugbọn èmi fúnra mi ni mo yọ̀ǹda rẹ̀. Mo ní àṣẹ láti yọ̀ǹda rẹ̀, mo ní àṣẹ láti tún gbà á pada. Àṣẹ yìí ni mo rí gbà láti ọ̀dọ̀ Baba mi.”

Ka pipe ipin Johanu 10

Wo Johanu 10:18 ni o tọ