Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 1:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Johanu jẹ́rìí nípa rẹ̀, ó ń ké rara pé, “Ẹni tí mo sọ nípa rẹ̀ nìyí pé, ‘Ẹnìkan ń bọ̀ lẹ́yìn mi tí ó jù mí lọ, nítorí ó ti wà ṣiwaju mi.’ ”

Ka pipe ipin Johanu 1

Wo Johanu 1:15 ni o tọ