Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ náà wá di eniyan, ó ń gbé ààrin wa, a rí ògo rẹ̀, ògo bíi ti Ọmọ bíbí kan ṣoṣo tí ó ti ọ̀dọ̀ Baba wá, tí ó kún fún oore-ọ̀fẹ́ ati òtítọ́.

Ka pipe ipin Johanu 1

Wo Johanu 1:14 ni o tọ