Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ìbẹ̀rẹ̀, kí á tó dá ayé, ni Ọ̀rọ̀ ti wà, Ọ̀rọ̀ wà pẹlu Ọlọrun, Ọlọrun sì ni Ọ̀rọ̀ náà.

Ka pipe ipin Johanu 1

Wo Johanu 1:1 ni o tọ