Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu Kinni 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Olùfẹ́, nisinsinyii ọmọ Ọlọrun ni wá. Ohun tí a óo dà kò ì tíì hàn sí wa. A mọ̀ pé nígbà tí Jesu Kristi bá yọ, bí ó ti rí ni àwa náà yóo rí, nítorí a óo rí i gẹ́gẹ́ bí ó ti rí.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 3

Wo Johanu Kinni 3:2 ni o tọ