Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu Kinni 3:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ wo irú ìfẹ́ tí Baba fẹ́ wa tí a fi ń pè wá ní ọmọ Ọlọrun! Bẹ́ẹ̀ gan-an ni a sì jẹ́. Nítorí náà, ayé kò mọ̀ wá, nítorí wọn kò mọ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 3

Wo Johanu Kinni 3:1 ni o tọ