Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu Kinni 2:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin baba, mo kọ ìwé si yín, nítorí pé ẹ ti mọ ẹni tí ó wà láti ìṣẹ̀dálẹ̀ ayé. Ẹ̀yin ọdọmọkunrin, mo kọ ìwé si yín, nítorí pé ẹ lágbára, ọ̀rọ̀ Ọlọrun ń gbé inú yín, ẹ sì ti ṣẹgun Èṣù.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 2

Wo Johanu Kinni 2:14 ni o tọ