Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Johanu Kinni 2:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀yin baba, mò ń kọ ìwé si yín, nítorí pé ẹ ti mọ ẹni tí ó wà láti ìṣẹ̀dálẹ̀ ayé. Ẹ̀yin ọdọmọkunrin, mò ń kọ ìwé si yín, nítorí pé ẹ ti ṣẹgun Èṣù. Ẹ̀yin ọmọde, mo kọ ìwé si yín, nítorí pé ẹ ti mọ Baba.

Ka pipe ipin Johanu Kinni 2

Wo Johanu Kinni 2:13 ni o tọ