Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 8:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó dáhùn pé, “Ó ṣe lè yé mi láìjẹ́ pé ẹnìkan bá ṣe àlàyé rẹ̀ fún mi?” Ó bá bẹ Filipi pé kí ó gòkè wọ inú ọkọ̀, kí ó jókòó ti òun.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 8

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 8:31 ni o tọ