Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 6:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn kan wá láti ilé ìpàdé kan tí à ń pè ní ti àwọn Olómìnira, ti àwọn ará Kurene ati àwọn ará Alẹkisandria; wọ́n tako Stefanu. Àwọn tí wọ́n wá láti Silisia ati láti Esia náà sì bẹ̀rẹ̀ sí bá a jiyàn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 6:9 ni o tọ