Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀rọ̀ Ọlọrun wá ń gbilẹ̀. Iye àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu túbọ̀ ń pọ̀ sí i ní Jerusalẹmu. Pupọ ninu àwọn alufaa ni wọ́n sì di onigbagbọ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 6

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 6:7 ni o tọ