Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 6:14-15 BIBELI MIMỌ (BM)

14. Nítorí a gbọ́ nígbà tí ó sọ pé Jesu ti Nasarẹti yóo wó ilé yìí, yóo yí àwọn àṣà tí Mose fún wa pada.”

15. Gbogbo àwọn tí ó jókòó ní ìgbìmọ̀ tẹjú mọ́ ọn, wọ́n rí ojú rẹ̀ tí ó dàbí ojú angẹli.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 6