Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 28:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ọkàn àwọn eniyan yìí kò ṣí; wọ́n ti di alágbọ̀ọ́ya,wọ́n ti dijú.Bí kò bá ṣe bẹ́ẹ̀,wọn ìbá fi ojú wọn ríran,wọn ìbá fetí gbọ́ràn,òye ìbá yé wọn,wọn ìbá yipada;èmi ìbá sì wò wọ́n sàn.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 28

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 28:27 ni o tọ