Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 21:30 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìlú bá dàrú. Àwọn eniyan ń rọ́ lọ sọ́dọ̀ Paulu. Wọ́n bá mú un, wọ́n wọ́ ọ jáde kúrò ninu Tẹmpili. Lẹsẹkẹsẹ wọ́n bá ti gbogbo ìlẹ̀kùn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 21:30 ni o tọ