Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Wọ́n kọjá ní Amfipoli ati Apolonia kí wọn tó dé Tẹsalonika. Ilé ìpàdé àwọn Juu kan wà níbẹ̀.

2. Gẹ́gẹ́ bí àṣà Paulu, ó wọ ibẹ̀ tọ̀ wọ́n lọ. Fún ọ̀sẹ̀ mẹta ni ó fi ń bá wọn fi ọ̀rọ̀ wé ọ̀rọ̀ láti inú Ìwé Mímọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 17