Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 17:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ń ṣe àlàyé fún wọn, ó tún ń tọ́ka sí àkọsílẹ̀ inú Ìwé Mímọ́ láti fihàn pé dandan ni kí Mesaya jìyà, kí ó jinde kúrò ninu òkú. Lẹ́yìn náà ó sọ fún wọn pé, Mesaya yìí náà ni Jesu tí òun ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ fún wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 17:3 ni o tọ