Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:48 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, ó pàṣẹ pé kí wọ́n ṣe ìrìbọmi ní orúkọ Jesu Kristi. Wọ́n bá bẹ̀ ẹ́ kí ó dúró lọ́dọ̀ wọn fún ọjọ́ díẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 10:48 ni o tọ