Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Aposteli 10:47-48 BIBELI MIMỌ (BM)

47. “Ta ló rí ohun ìdíwọ́ kan, ninu pé kí á ṣe ìrìbọmi fún àwọn wọnyi, tí wọ́n gba Ẹ̀mí Mímọ́ bí àwa náà ti gbà á?”

48. Lẹ́yìn náà, ó pàṣẹ pé kí wọ́n ṣe ìrìbọmi ní orúkọ Jesu Kristi. Wọ́n bá bẹ̀ ẹ́ kí ó dúró lọ́dọ̀ wọn fún ọjọ́ díẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 10