Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ẹ máa gba ara yín níyànjú lojoojumọ níwọ̀n ìgbà tí ọ̀rọ̀ “Òní” tí Ìwé Mímọ́ sọ bá ti bá àwa náà wí, kí ẹ̀ṣẹ̀ má baà tan ẹnikẹ́ni lọ, kí ó sì mú kí ó ṣe agídí sí Ọlọrun.

Ka pipe ipin Heberu 3

Wo Heberu 3:13 ni o tọ