Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 2:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun pàápàá tún jẹ́rìí sí ọ̀rọ̀ náà nípa àwọn àmì ati iṣẹ́ ìyanu ati oríṣìíríṣìí iṣẹ́ tí ó ju agbára ẹ̀dá lọ, tí ó ṣe nípa Ẹ̀mí Mímọ́ tí ó pín gẹ́gẹ́ bí ìfẹ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Heberu 2

Wo Heberu 2:4 ni o tọ