Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

báwo ni a óo ti ṣe sá àsálà, tí a bá kọ etí-ikún sí ìgbàlà tí ó tóbi tó báyìí? Oluwa fúnrarẹ̀ ni ó kọ́kọ́ kéde ìgbàlà yìí ní ìbẹ̀rẹ̀. Àwọn tí wọ́n gbọ́ ni wọ́n fún wa ní ìdánilójú pé bẹ́ẹ̀ ni ó rí.

Ka pipe ipin Heberu 2

Wo Heberu 2:3 ni o tọ