Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má jẹ́ kí ìfẹ́ owó gbà yín lọ́kàn. Ẹ ní ìtẹ́lọ́rùn pẹlu ohun tí ẹ ní. Nítorí Ọlọrun fúnrarẹ̀ ti sọ pé, “N kò ní fi ọ́ sílẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni n kò ní kọ̀ ọ́!”

Ka pipe ipin Heberu 13

Wo Heberu 13:5 ni o tọ