Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn wọnyi kú ninu igbagbọ. Wọn kò rí ohun tí Ọlọrun ṣe ìlérí gbà, òkèèrè ni wọ́n ti rí i, wọ́n sì ń fi ayọ̀ retí rẹ̀. Wọ́n jẹ́wọ́ pé àlejò tí ń rékọjá lọ ni àwọn ní ayé.

Ka pipe ipin Heberu 11

Wo Heberu 11:13 ni o tọ