Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Heberu 11:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí èyí, láti ọ̀dọ̀ ẹyọ ọkunrin kan, tí ó ti dàgbà títí, tí ó ti kú sára, ni ọpọlọpọ ọmọ ti jáde, wọ́n pọ̀ bíi ìràwọ̀ ojú ọ̀run, ati bíi iyanrìn etí òkun.

Ka pipe ipin Heberu 11

Wo Heberu 11:12 ni o tọ