Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Galatia 3:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé nítorí pé ẹ̀ ń ṣe iṣẹ́ òfin ni ẹni tí ó fi ẹ̀bùn Ẹ̀mí fun yín ṣe fun yín lẹ́kùn-únrẹ́rẹ́, tí ó tún ṣiṣẹ́ ìyanu láàrin yín, tabi nítorí pé ẹ gbọ́ ìyìn rere, ẹ sì gbà á?

Ka pipe ipin Galatia 3

Wo Galatia 3:5 ni o tọ