Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Galatia 1:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ẹ̀sìn Juu, mo ta ọpọlọpọ àwọn ẹlẹgbẹ́ mi ninu orílẹ̀-èdè mi yọ. Mo ní ìtara rékọjá ààlà ninu àṣà ìbílẹ̀ àwọn baba-ńlá mi.

Ka pipe ipin Galatia 1

Wo Galatia 1:14 ni o tọ