Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Galatia 1:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹ ti gbúròó ìwà mi látijọ́ nígbà tí mo wà ninu ẹ̀sìn ti Juu, pé mò ń fìtínà ìjọ Ọlọrun ju bí ó ti yẹ lọ. Mo sa gbogbo ipá mi láti pa á run.

Ka pipe ipin Galatia 1

Wo Galatia 1:13 ni o tọ