Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanaya 3:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ìwọ ìlú ọlọ̀tẹ̀, o gbé! Ìlú oníbàjẹ́ ati aninilára.

2. Ìlú tí kò gba ìmọ̀ràn ati ìbáwí, tí kò gbẹ́kẹ̀lé OLUWA, tí kò sì súnmọ́ Ọlọrun rẹ̀.

Ka pipe ipin Sefanaya 3